Leviticus 8:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ta díẹ̀ ninu òróró náà sí Aaroni lórí láti yà á sí mímọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si dà ninu oróro itasori si ori Aaroni, o si ta a si i lara, lati yà a simimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ó da díẹ̀ lára òróró ìtasórí yìí sórí Árónì, ó sì yà á sí mímọ́.