Leviticus 8:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n gé ẹran àgbò náà sí wẹ́wẹ́, ó sun gbogbo rẹ̀ pẹlu orí rẹ̀ ati ọ̀rá rẹ̀ lórí pẹpẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si kun àgbo na; Mose si sun ori rẹ̀, ati ara rẹ̀, ati ọrá na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó gé àgbò náà sí wẹ́wẹ́, ó sì sun orí àti àwọn ègé àti ọ̀rá rẹ̀.