Leviticus 8:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ sì ṣe gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ láti ẹnu Mose.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li Aaroni ati awọn ọmọ rẹ̀ ṣe ohun gbogbo ti OLUWA ti fi aṣẹ lelẹ lati ọwọ́ Mose wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe ohun gbogbo tí OLÚWA pa láṣẹ láti ẹnu Mósè.