Leviticus 9:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ọjọ́ kẹjọ, Mose pe Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ati àwọn àgbààgbà Israẹli;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe ni ijọ́ kẹjọ, ni Mose pè Aaroni ati awọn ọmọ rẹ̀, ati awọn àgba Israeli;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ kẹjọ, Mósè pe Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì.