Leviticus 9:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ó mú àwọn igẹ̀ ẹran náà ati itan ọ̀tún wọn, ó fì wọ́n gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fífì níwájú OLUWA, bí Mose ti pa á láṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati igẹ̀ na ati itan ọtún ni Aaroni fì li ẹbọ fifì niwaju OLUWA; bi Mose ti fi aṣẹ lelẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Árónì fí igẹ̀ àti itan ọ̀tún ẹran náà níwájú OLÚWA gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fífì bí Mósè ṣe pa á láṣẹ.