Leviticus 9:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mose sọ fún wọn pé, “Ohun tí OLUWA paláṣẹ fun yín láti ṣe nìyí, ògo OLUWA yóo hàn sí yín.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si wipe, Eyi li ohun ti OLUWA filelẹ li aṣẹ, ki ẹnyin ki o ṣe: ogo OLUWA yio si farahàn nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Mósè wí pé, “Ohun tí OLÚWA pa láṣẹ fún yín láti ṣe nìyìí, kí ògo OLÚWA bá à lè farahàn yín.”