Luke 1:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ọpọlọpọ àwọn ọmọ Israẹli ni yóo sì yipada sí Oluwa Ọlọrun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si pa pipọ da ninu awọn ọmọ Israeli si Oluwa Ọlọrun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun ó sì yí ènìyàn púpọ̀ padà nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí Olúwa Ọlọ́run wọn.