Luke 1:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
àwọn tí nǹkan wọnyi ṣojú wọn, tí wọ́n sì sọ fún wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ani gẹgẹ bi awọn ti o ṣe oju wọn lati ibẹrẹ, ti nwọn si jasi iranṣẹ ọrọ na, ti fi le wa lọwọ;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àní gẹ́gẹ́ bí àwọn ìránṣẹ́ ọ̀rọ̀ náà tí ó ṣe ojú wọn láti ìbẹ̀rẹ̀ ti fi lé wa lọ́wọ́.