Luke 1:51 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ fi agbára rẹ̀ hàn, ó tú àwọn tí ó gbéraga ninu ọkàn wọn ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti fi agbara hàn li apa rẹ̀; o ti tú awọn onirera ká ni ironu ọkàn wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ti fi agbára hàn ní apá rẹ̀; Ó ti tú àwọn onígberaga ká ní ìrònú ọkàn wọn.