Luke 13:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà Jesu sọ pé, “Kí ni à bá fi ìjọba Ọlọrun wé? Kí ni ǹ bá fi ṣe àkàwé rẹ̀?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wipe, Kini ijọba Ọlọrun jọ? kili emi o si fi wé?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wí pé, “Kíni ìjọba Ọlọ́run jọ? Kíni èmi ó sì fi wé?