Luke 18:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìjòyè náà dáhùn pé, “Gbogbo òfin wọnyi ni mo ti ń pamọ́ láti ìgbà tí mo ti wà ní ọdọmọkunrin.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wipe, Gbogbo nkan wọnyi li emi ti pamọ lati igba ewe mi wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wí pé, “Gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni èmi ti pa mọ́ láti ìgbà èwe mi wá.”