Luke 18:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n bá nà án tán, wọn óo sì pa á. Ṣugbọn ní ọjọ́ kẹta, yóo jí dìde.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o si nà a, nwọn o si pa a: ni ijọ kẹta yio si jinde.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ó sì nà án, wọn ó sì pa á: ní ijọ́ kẹ́ta yóò sì jíǹde.”