Luke 20:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ìgbẹ̀yìn-gbẹ́yín, obinrin náà alára wá kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nikẹhin gbogbo wọn, obinrin na kú pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbẹ̀yìn pátápátá obìnrin náà kú pẹ̀lú.