Luke 20:45 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní etí gbogbo àwọn eniyan, Jesu sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ li etí gbogbo enia pe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ní etí gbogbo ènìyàn pé,