Luke 21:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ọjọ́ náà yóo dé bá gbogbo eniyan tí ó wà ní ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori bẹni yio de ba gbogbo awọn ti ngbe ori gbogbo ilẹ aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí bẹ́ẹ̀ ni yóò dé bá gbogbo àwọn tí ń gbé orí gbogbo ilẹ̀ ayé.