Luke 21:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo eniyan a máa tètè jí láti lọ gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ ninu Tẹmpili.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo enia si ntọ̀ ọ wá ni tẹmpili ni kutukutu owurọ̀, lati gbọ́rọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ènìyàn sì ń tọ̀ ọ́ wá ní tẹ́ḿpílì ní kùtùkùtù òwúrọ̀, láti gbọ́rọ̀ rẹ̀.