Luke 22:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ó tó àkókò oúnjẹ, ó jókòó láti jẹun pẹlu àwọn aposteli rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati akokò si to, o joko ati awọn aposteli pẹlu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àkókò sì tó, ó jókòó àti àwọn àpósítélì pẹ̀lú rẹ̀.