Luke 22:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìjiyàn kan wà láàrin àwọn ọmọ-ẹ̀yìn pé ta ni ó jẹ́ ẹni pataki jùlọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ijà kan si mbẹ larin wọn, niti ẹniti a kà si olori ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìjà kan sì ń bẹ láàrin wọn, ní ti ẹni tí a kà sí olórí níńu wọn.