Luke 22:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ẹ̀yin ni ẹ dúró tì mí ní gbogbo àkókò ìdánwò mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin li awọn ti o ti duro tì mi ninu idanwo mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin ni àwọn tí ó ti dúró tì mí nínú ìdánwò mi,