Luke 23:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ó níláti dá ẹlẹ́wọ̀n kan sílẹ̀ fún wọn ní àkókò àjọ̀dún.]
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn kò le ṣe aidá ọkan silẹ fun wọn nigba ajọ irekọja.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Ṣùgbọ́n kò lè ṣàì dá ọ̀kan sílẹ̀ fún wọn nígba àjọ ìrékọjá.)