Luke 23:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n tún ń fa àwọn arúfin meji kan pẹlu rẹ̀, láti lọ pa wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si fà awọn meji lọ pẹlu, awọn arufin, lati pa pẹlu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn méjì mìíràn bákàn náà, àwọn arúfin, ni wọ́n sì fà lọ pẹ̀lú rẹ̀ láti pa.