Luke 23:55 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn obinrin tí wọn bá Jesu wá láti Galili tẹ̀lé Josẹfu yìí, wọ́n ṣe akiyesi ibojì náà, ati bí a ti ṣe tẹ́ òkú Jesu sinu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn obinrin, ti nwọn bá a ti Galili wá, ti nwọn si tẹle, nwọn kiyesi ibojì na, ati bi a ti tẹ́ okú rẹ̀ si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn obìnrin, tí wọ́n bá a ti Gálílì wá, tí wọ́n sì tẹ̀lé, wọ́n kíyèsí ibojì náà, àti bí a ti tẹ́ òkú rẹ̀ sílẹ̀.