Luke 24:45 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó bá là wọ́n lọ́yẹ kí Ìwé Mímọ́ lè yé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li o ṣí wọn ni iyè, ki iwe-mimọ́ ki o le yé wọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó ṣí wọn níyè, kí ìwé mímọ́ lè yé wọn.