Luke 5:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn ninu àpò awọ titun ni wọ́n ń fi ọtí titun sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ọti-waini titun li a ifi sinu igo titun; awọn mejeji a si ṣe dede.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, ó tọ́ kí á da wáìnì tuntun sínú awọ tuntun.