Luke 6:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n wá gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ ati pé kí ó lè wò wọ́n sàn kúrò ninu àìsàn wọn. Ó tún ń wo àwọn tí ẹ̀mí Èṣù ń dà láàmú sàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ti ara kan fun ẹmi aimọ́: a si mu wọn larada.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn tí ara wọn kún fún ẹ̀mí àìmọ́; ni ó sì mú láradá.