Luke 7:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Jesu parí ọ̀rọ̀ tí ó ń bá àwọn eniyan sọ, ó wọ inú ìlú Kapanaumu lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBATI o si pari gbogbo ọ̀rọ rẹ̀ li eti awọn enia, o wọ̀ Kapernaumu lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó sì pari gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ létí àwọn ènìyàn, ó wọ Kápánáúmù lọ.