Luke 7:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu ròyìn gbogbo nǹkan wọnyi fún un. Johanu bá pe meji ninu wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ-ẹhin Johanu si fi ninu gbogbo nkan wọnyi hàn fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jòhánù sì sọ gbogbo nǹkan wọ̀nyí fún un.