Luke 7:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jesu tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ bọ̀, ó ní, “Ta ni èmi ìbá fi àwọn eniyan òde òní wé? Ta ni kí a wí pé wọ́n jọ?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa si wipe, Kili emi iba fi awọn enia iran yi wé? kini nwọn si jọ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olúwa sì wí pé, “Kí ni èmi ìbá fi àwọn ènìyàn ìran yìí wé? Kí ni wọ́n sì jọ?