Luke 9:46 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àríyànjiyàn kan bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu lórí pé ta ló ṣe pataki jùlọ láàrin wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iyan kan si dide lãrin wọn, niti ẹniti yio ṣe olori ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iyàn kan sì dìde láàrin wọn, ní ti ẹni tí yóò ṣe olórí nínú wọn.