Malachi 1:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Mo fẹ́ràn yín pupọ.” Ṣugbọn ẹ̀ ń bèèrè pé, “Kí ló fihàn pé o fẹ́ràn wa?” OLUWA dáhùn pé, “Ṣebí tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni Esau ati Jakọbu?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti fẹ nyin, li Oluwa wi. Ṣugbọn ẹnyin wipe, Ninu kili o fẹ wa? Arakunrin Jakobu ki Esau iṣe? li Oluwa wi: bẹli emi sa fẹ Jakobu,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmí ti fẹ́ ẹ yín,” ni OLÚWA wí. “Ṣùgbọ́n ẹ̀yín béèrè pé, ‘Báwo ni ìwọ ṣe fẹ́ wa?’ “Ísọ̀ kì í ha ṣe arákùnrin Jákọ́bù bí?” ni OLÚWA wí. “Ṣíbẹ̀ èmi fẹ́ràn Jákọ́bù,