Malachi 3:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ègún wà lórí gbogbo yín nítorí pé gbogbo orílẹ̀-èdè yín ní ń jà mí lólè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Riré li a o fi nyin ré: nitori ẹnyin ti jà mi li olè, ani gbogbo orilẹ-ède yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ríré ni a ó fi yín ré: gbogbo orílẹ̀ èdè yìí, nítorí ẹ̀yin ti jà mi lólè.