Mark 10:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Jesu wí fún wọn pé, “Nítorí oríkunkun yín ni Mose fi kọ òfin yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jesu si da wọn lohùn, o si wi fun wọn pe, Nitori lile àiya nyin li o ṣe kọ irú ofin yi fun nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Jésù dá wọn lóhùn, ó sì wí pé, “Mósè kọ òfin yìí fun un yín nítorí ẹ jẹ́ ọlọ́kàn líle.