Mark 11:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àbí kí a wí pé, ‘Láti ọwọ́ eniyan ni?’ ” Wọ́n bẹ̀rù àwọn eniyan nítorí gbogbo eniyan ni ó gbà pé wolii tòótọ́ ni Johanu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi awa ba wipe, Lati ọdọ enia; nwọn bẹ̀ru awọn enia: nitori gbogbo enia kà Johanu si woli nitõtọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n bí a bá sọ wí pé Ọlọ́run kọ́ ló rán an, nígbà náà àwọn ènìyàn yóò bẹ̀rẹ̀ rògbòdìyàn. Nítorí pé gbogbo ènìyàn ló gbàgbọ́ pé wòlíì gidi ni Jòhánù.”