Mark 11:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n bá dá Jesu lóhùn pé, “Àwa kò mọ̀.” Nígbà náà ni Jesu sọ fún wọn pé, “Èmi náà kò ní sọ irú àṣẹ tí mo fi ń ṣe àwọn nǹkan wọnyi fun yín.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si dahùn wi fun Jesu pe, Awa kó mọ̀. Jesu si dahùn wi fun wọn pe, Emi kì yio si wi fun nyin aṣẹ ti emi fi nṣe nkan wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, Wọ́n kọjú sí Jésù wọn sì dáhùn pé, “Àwa kò mọ̀.” Nígbà náà ni Jésù wí pé, “Níwọ̀n ìgbà tí ẹ kò lè dáhùn ìbéèrè mi, Èmi náà kì yóò sọ fún yín àṣẹ tí mo fi ń ṣe nǹkan wọ̀nyí.”