Mark 11:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kan tí wọ́n ti jókòó níbẹ̀ bi wọ́n pé, “Kí ló dé tí ẹ̀ ń tú kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn kan ninu awọn ti o duro nibẹ̀ wi fun wọn pe, Kili ẹnyin nṣe, ti ẹnyin fi ntú ọmọ kẹtẹkẹtẹ nì?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n ti ń tú u, díẹ̀ nínú àwọn tí ó dúró níbẹ̀ bi wọ́n léèrè pé, “Kí ni ẹ̀ ń ṣe, È ń tú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́?”