Mark 11:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n bá dá wọn lóhùn gẹ́gẹ́ bí Jesu ti wí fún wọn. Àwọn eniyan náà sì yọ̀ǹda fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si wi fun wọn gẹgẹ bi Jesu ti wi fun wọn: nwọn si jọwọ wọn lọwọ lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì wọ̀nyí sọ ohun tí Jésù ní kí wọ́n sọ. Nítorí náà àwọn ènìyàn náà yọ̀ǹda fún wọn láti mú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà lọ.