Mark 11:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n bá fa kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà wá sí ọ̀dọ̀ Jesu, wọ́n tẹ́ aṣọ wọn sí orí rẹ̀, Jesu bá gùn un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si fà ọmọ kẹtẹkẹtẹ na tọ̀ Jesu wá, nwọn si tẹ́ aṣọ wọn si ẹ̀hin rẹ̀; on si joko lori rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n mú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà tọ Jésù wá. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì bọ́ ẹ̀wù wọn, wọ́n sì tẹ́ ẹ sí ẹ̀yìn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà fún Jésù láti jókòó lórí rẹ̀.