Mark 11:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọpọlọpọ eniyan tẹ́ aṣọ wọn sí ọ̀nà, àwọn mìíràn tẹ́ ẹ̀ka igi tí wọ́n ya ní pápá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn pipọ si tẹ́ aṣọ wọn si ọ̀na: ati awọn miran ṣẹ́ ẹ̀ka igi, nwọn si fún wọn si ọ̀na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, púpọ̀ nínú ọ̀pọ̀ ènìyàn tẹ́ àṣọ wọn sójú-ọ̀nà níwájú u rẹ̀. Àwọn mìíràn ju ewéko ìgbẹ́ sílẹ̀.