Mark 12:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ kò ì tíì kà ninu Ìwé Mímọ́, pé, ‘Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀ ni ó di pataki igun ilé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin kò ha ti kà iwe-mimọ yi; Okuta ti awọn ọmọle kọ̀ silẹ on na li o di pàtaki igun ile:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tàbí ẹ̀yin kò ì tí ka ẹṣẹ yìí nínú ìwé mímọ́: “ ‘Òkúta tí àwọn ọmọ̀lé ti kọ̀ sílẹ̀ òun náà ni ó di pàtàkì igun ilé.