Mark 14:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ó di ìrọ̀lẹ́, Jesu wá sibẹ pẹlu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati alẹ lẹ, o wá pẹlu awọn mejila.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó di alẹ́, Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dé ṣíbẹ̀.