Mark 14:50 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni Gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bá fi í sílẹ̀, wọ́n bá sálọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo wọn si fi i silẹ, nwọn si sá lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àkókò yìí, gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti fi í sílẹ̀, wọ́n sá lọ.