Mark 14:59 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹ ẹ̀rí wọn kò bá ara wọn mu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu eyi na pẹlu, ohùn wọn kò ṣọkan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀, ẹ̀rí i wọn kò dọ́gba