Mark 15:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni gbogbo wọn kígbe pé, “Kàn án mọ́ agbelebu!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si tún kigbe soke, wipe, Kàn a mọ agbelebu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì tún kígbe sókè pé, “Kàn án mọ àgbélébùú!”