Mark 15:45 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ó gbọ́ ìròyìn ọ̀gágun náà, ó yọ̀ǹda òkú Jesu fún Josẹfu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o si mọ̀ lati ọdọ balọgun ọrún na, o si fi okú na fun Josefu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí balógun-ọ̀rún náà sì fún Pílátù ni ìdánilójú pé Jésù ti kú, Pílátù yọ̀ǹda òkú rẹ̀ fún Jóṣẹ́fù.