Mark 3:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn kan wà tí wọn ń ṣọ́ ọ bí yóo wo ọkunrin yìí sàn ní Ọjọ́ Ìsinmi, kí wọn lè fi í sùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si nṣọ ọ, bi yio mu u larada li ọjọ isimi; ki nwọn ki o le fi i sùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọ́n kan nínú wọn sì ń wa ọ̀nà láti fi ẹ̀sùn kan Jésù, ítorí náà, wọn ń sọ Ọ́ bí yóò u un láradá ní ọjọ́ ìsinmi.