Mark 3:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
(Jesu sọ èyí nítorí wọ́n ń wí pé ó ní ẹ̀mí Èṣù.)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti nwọn wipe, O li ẹmi aimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun sọ eléyìí fún wọn, nítorí tí wọ́n sọ pé, “Nípa agbára ẹ̀mí Èṣù ló ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀.”