Mark 3:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó dá wọn lóhùn pé, “Ta ni ìyá mi ati arakunrin mi?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si da wọn lohùn, wipe, Tani iṣe iya mi, tabi awọn arakunrin mi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó dá wọn lóhùn wí pé, “Ta ni í ṣe ìyá mi tàbí àwọn arákùnrin mi?”
Recommended Reading