Mark 4:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà Jesu ní, “Ẹni tí ó bá ní etí láti fi gbọ́ràn, kí ó gbọ́!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wi fun wọn pe, Ẹniti o ba li etí lati fi gbọ, ki o gbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jésù sì wí pé, “Ẹni tí ó bá ní etí láti fi gbọ́, kí ó gbọ́”