Mark 6:43 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n bá kó àjẹkù burẹdi ati ẹja jọ, ó kún agbọ̀n mejila.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si kó agbọ̀n mejila kún fun ajẹkù, ati ti ẹja pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì kó agbọ̀n méjìlá tí ó kún fún àjẹkù àkàrà àti ti ẹja pẹ̀lú.