Mark 6:46 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ó ti dágbére fún wọn, ó lọ sí orí òkè, ó lọ gbadura.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o si rán wọn lọ tan, o gùn ori òke lọ igbadura.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà, ó lọ sórí òkè láti lọ gbàdúrà.